Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Rùwáńdà

 

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní Orílẹ̀-èdè Rùwáńdà

  • Iye àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà​—33,664

  • Iye àwọn ìjọ​—593

  • Iye àwọn tó wá síbi Ìrántí Ikú Kristi​—105,966

  • Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún​—418

  • Iye èèyàn​—13,246,000

2020-02-17

RÙWÁŃDÀ

Wọ́n Rántí Ìpẹ̀yàrun Tó Ṣẹlẹ̀ Ní Rùwáńdà Lẹ́yìn Ọdún Márùndínlọ́gbọ̀n

Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan rántí bí ìpẹ̀yàrun tó wáyé lọ́dún 1994 lórílẹ̀-èdè Rùwáńdà ṣe dá wàhálà sílẹ̀, ó sì ṣàlàyé bí ìfẹ́ ìfara-ẹni rúbọ tí wọ́n ní sí i ṣe gba ẹ̀mí rẹ̀ là.

2016-10-06

RÙWÁŃDÀ

Ìjọba Orílẹ̀-èdè Rùwáńdà Gbé Ìgbésẹ̀ Láti Fòpin sí Ẹ̀tanú Ẹ̀sìn Níléèwé

Ìtura gbáà ló jẹ́ fáwọn ọmọ iléèwé tí wọ́n jẹ́ Ẹlẹ́rìí pé ìjọba gbé ìgbésẹ̀ láti gbèjà àwọn ọmọ iléèwé kí wọ́n lè ní òmìnira ẹ̀sìn.