Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Zambia

Ìsọfúnni Ṣókí—Zambia

  • 20,018,000—Iye àwọn èèyàn
  • 239,427—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 3,605—Iye àwọn ìjọ
  • 95—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Dayrell Sharp: Jèhófà Ni Ò Jẹ́ Ká Fà Sẹ́yìn

Láìka àwọn ìṣòro tí wọ́n kojú sí, Dayrell àti Susanne Sharp ran àwọn tó lé ní àádóje lọ́wọ́ láti ṣèrìbọmi.