Ìsọfúnni Ṣókí—Venezuela
- 28,302,000—Iye àwọn èèyàn
- 134,096—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 1,700—Iye àwọn ìjọ
- 215—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
ÌRÍRÍ
Wọ́n Ń Sin Jèhófà Láìka Bí Nǹkan Ṣe Le Tó Lórílẹ̀-Èdè Fẹnẹsúélà
Àwọn ará wa lórílẹ̀-èdè Fẹnẹsúélà ń fìtara wàásù, wọ́n sì jẹ́ “orísun ìtùnú” fún ara wọn.
BÁ A ṢE Ń NÁ OWÓ TẸ́ Ẹ FI Ń ṢÈTỌRẸ
Bá A Ṣe Pèsè Ìrànwọ́ Lọ́dún 2021—A Ò Pa Àwọn Arákùnrin Àtàwọn Arábìnrin Wa Tì
Lọ́dún 2021, a ṣèrànwọ́ fáwọn ará wa láwọn orílẹ̀-èdè kan tí àrùn Corona àtàwọn àjálù míì ti fojú wọn rí màbo.
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
Mo Máa Ń Ro Ti Jèhófà Tí Mo Bá Ń Ṣèpinnu
Ìtàn ìgbésí ayé: Dyah Yazbek
ÌRÒYÌN
Ìròyìn Láti Fẹnẹsúélà: Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Túbọ̀ Tẹra Mọ́ Ìjọsìn Ọlọ́run Láìka Ìṣòro Sí
Bó tiẹ̀ jẹ́ pé nǹkan nira gan-an, àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní Fẹnẹsúélà ò yéé fìgboyà wàásù.