Ìsọfúnni Ṣókí—United States of America
- 336,679,000—Iye àwọn èèyàn
- 1,233,609—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 11,942—Iye àwọn ìjọ
- 276—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
ÌRÍRÍ
Ìrànlọ́wọ́ fún Àwọn Òṣìṣẹ́ Ilé Ìwòsàn Tó Ń Fara Da Àárẹ̀
Ibo làwọn nọ́ọ̀sì àtàwọn ọ̀ṣìṣẹ́ ilé ìwòsàn kan ti rí ìṣírí nígbà àjàkálẹ̀ àrùn Corona?
BÍ NǸKAN ṢE RÍ NÍ BẸ́TẸ́LÌ
A Pè Ẹ́ Kó O Wá Wo Àwọn Ọ́fíìsì Wa Tó Wà ní Bẹ́tẹ́lì Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà
Wàá rí Oríléeṣẹ́ Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà àti ẹ̀ka ọ́fíìsì wa lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú —ní New York
Kí nìdí tí tọkọtaya kan tó rí towó ṣe fi kó kúrò nínú ilé ńlá tí wọ́n nífẹ̀ẹ́ sí gan-an, tí wọ́n sì kó lọ sí yàrá kékeré kan?