Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

New Zealand

  • Etíkun Waitemata, Auckland, New Zealand​—Wọ́n ń wàásù fún apẹja kan láìjẹ́-bí-àṣà

Ìsọfúnni Ṣókí—New Zealand

  • 5,199,000—Iye àwọn èèyàn
  • 14,607—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 170—Iye àwọn ìjọ
  • 360—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

LÁTINÚ ÀPAMỌ́ WA

Ṣé Èèyàn Àlàáfíà àti Kristẹni Tòótọ́ Làwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní New Zealand?

Ní àwọn ọdún 1940, kí nìdí tí wọ́n fi ka àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà sí ewu fún àwọn ará ìlú?

JÍ!

Jẹ́ ká lọ sí orílẹ̀-èdè New Zealand

Bó tilẹ̀ jẹ́ pé orílè-èdè New Zealand kò fi bẹ́ẹ̀ gbajúmọ̀ síbẹ̀ nǹkan bí mílíọ̀nù mẹ́ta [3,000,000] èèyàn ló máa ń rìnrìn-àjò afẹ́ lọ síbẹ̀ lọ́dọọdún. Kí ló mú kí wọ́n máa lọ síbẹ̀?