Ìsọfúnni Ṣókí—Norway
- 5,504,000—Iye àwọn èèyàn
- 12,034—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 162—Iye àwọn ìjọ
- 464—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú—ní Norway
Báwo ni ìbéèrè kan tó wá láìròtẹ́lẹ̀ ṣe mú kí ìdílé kan kó lọ síbi tá a ti nílò àwọn oníwàásù púpọ̀ sí i?