Ìsọfúnni Ṣókí—Guam
- 173,000—Iye àwọn èèyàn
- 709—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 9—Iye àwọn ìjọ
- 250—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú —Ní Micronesia
Ó kéré tán ìpèníjà mẹ́ta làwọn tó ti òkèèrè wá sìn ní erékùṣù Pàsífí ìkì sábà máa ń ní. Àmọ́, kí ló ran àwọn àkéde yìí lọ́wọ́?