Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

France

  • Paris, France​—Wọ́n ń sọ ohun tó wà nínú Bíbélì nítòsí Odò Seine

Ìsọfúnni Ṣókí—France

  • 64,793,000—Iye àwọn èèyàn
  • 138,133—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 1,461—Iye àwọn ìjọ
  • 474—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

“Jèhófà Mú Yín Wá sí Ilẹ̀ Faransé Láti Kẹ́kọ̀ọ́ Òtítọ́”

Ìwé àdéhùn tí ìjọba orílẹ̀-èdè Poland àti ti ilẹ̀ Faransé ti ọwọ́ bọ̀ ní ọdún 1919 ní àbájáde tí wọn kò rò tẹ́lẹ̀.

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

“Ohunkóhun Ò Gbọ́dọ̀ Dí Yín Lọ́wọ́!”

Àwọn òjíṣẹ́ alákòókò kíkún tó wà nílẹ̀ Faransé láwọn ọdún 1930 sí ọdún 1939 fi àpẹẹrẹ tó dáa lélẹ̀ tó bá dọ̀rọ̀ ká ní ìtara àti ìfaradà.