Ìsọfúnni Ṣókí—Denmark
- 5,941,000—Iye àwọn èèyàn
- 14,639—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 172—Iye àwọn ìjọ
- 410—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
Ebeltoft, Denmark—Wọ́n ń fún ẹnì kan ní àṣàrò kúkúrú náà, Kí Ló Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀?