Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Canada

  • Montreal, Canada—Wọ́n ń fún ẹnì kan ní Ilé Ìṣọ́

Ìsọfúnni Ṣókí—Canada

  • 38,704,000—Iye àwọn èèyàn
  • 120,388—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 1,164—Iye àwọn ìjọ
  • 325—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ÌRÒYÌN

Ilé Ẹjọ́ Gíga Jù Lọ ti Kánádà Kọ̀ Láti Dá sí Ètò Ìyọlẹ́gbẹ́

Ibi tí Ilé Ẹjọ́ Gíga Jù Lọ ti Kánádà parí èrò sí ni pé ètò ìyọlẹ́gbẹ́ “kì í ṣe èyí tó ní ìkórìíra nínú, kàkà bẹ́ẹ̀, ṣe ló máa ń jẹ́ kí wọ́n lè ran ẹni náà lọ́wọ́ kó lè pa dà di ara Ìjọ.”

IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

Iṣẹ́ Ìwàásù Ní Àwọn Ìgbèríko Lórílẹ̀-Èdè Kánádà

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà wàásù fún àwọn tó wà ní ìgbèríko lédè ìbílẹ̀ wọn kí gbogbo wọ́n lè gbọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run.

ÌRÒYÌN

A Rántí Àwọn Ará Wa Tó Nígbàgbọ́ ní Àgọ́ Tí Wọ́n Ti Ń Fipá Múni Ṣiṣẹ́ ní Kánádà

Ó ti pé ọdún márùndínlọ́gọ́rin (75) tí wọ́n dá àwọn arákùnrin wa sílẹ̀ láwọn àgọ́ tí wọ́n ti ń fipá múni ṣiṣẹ́ ní Kánádà. Wọ́n jù wọ́n sẹ́wọ̀n torí pé ẹ̀rí ọkàn wọn ò gbà wọ́n láyè láti wọṣẹ́ ológun.