Ìsọfúnni Ṣókí—Austria
- 9,105,000—Iye àwọn èèyàn
- 22,443—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 283—Iye àwọn ìjọ
- 411—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
Ìlú Kan ní Austria Yin Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Mọ́kànlélọ́gbọ̀n[31], Tí Wọ́n Ṣẹ́ Níìṣẹ́ Lábẹ́ Ìjọba Násì
Wọ́n ṣe àmì ẹ̀yẹ kan ní ìlú Techelsberg láti rántí àwọn Ẹlẹ́rìí tí ìjọba Násì fìyà jẹ nígba Ogun Àgbáyẹ́ Kejì
BÁ A ṢE Ń RAN ARÁ ÌLÚ LỌ́WỌ́
Wọ́n Ń Ran Àwọn tí Ogun Lé Wá sí Àárín Gbùngbùn Yúróòpù Lọ́wọ́
Kì í ṣe oúnjẹ, aṣọ àti ilé nìkan làwọn tí ogun lé kúrò nílùú nílò. Àwọn Ẹlẹ́rìí tó yọ̀ǹda ara wọn ń sọ̀rọ̀ ìtùnú àti ọ̀rọ̀ táá jẹ́ kí wọ́n nírètí fún wọn látinú Bíbélì.
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
Baba Kú, àmọ́ Baba Kù
Ka ìtàn ìgbésí ayé Gerrit Lösch, tó jẹ́ ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí.
Ilé Ẹjọ́ Ní Kí ìjọba Austria San Owó Máà-Bínú fún Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà
Ní September 25, ọdún 2012, Ilé Ẹjọ́ Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn ti Ilẹ̀ Yúróòpù tó wà ní ìlú Strasbourg, ní orílẹ̀-èdè Faransé dájọ́ pé ìjọba Austria jẹ̀bi ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn án pé ó ṣe ẹ̀tanú sí àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà.