ERÉ ALÁWÒRÁN
Jésù Fọ Tẹ́ńpìlì Mọ́
Wa eré aláwòrán yìí jáde kí o sì tẹ̀ ẹ́, ya àwòrán náà tán, kí ìwọ àti ìdílé rẹ jọ dáhùn àwọn ìbéèrè tó wà níbẹ̀.