Ẹ̀kọ́ 17: Dáàbò Bo Ọmọ Rẹ
Ẹ̀yin òbí, ẹ dáàbò bo àwọn ọmọ yín lọ́wọ́ ewu!
O Tún Lè Wo
ERÉ DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ
Dán Àláàmù Rẹ Wò!
Kí làwọn òbí lè ṣe láti dáàbò bo àwọn ọmọ wọn kí nǹkan má bàa ṣe wọ́n?
Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ
Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé
Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.