Awon Ere Bebi Ti Awon Omode Gbadun Gan-an
Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣe àwọn fídíò eré bèbí tó ń kọ́ àwọn ọmọdé bí wọ́n á ṣe máa tẹ̀ lé àwọn ìlànà inú Bíbélì. Báwo la ṣe ń ṣe àwọn fídíò yìí, báwo ni àwọn ọmọdé sì ṣe ń gbádùn rẹ̀ sí? Wàá rí ìdáhùn tó o bá wo fídíò yìí.
O Tún Lè Wo
Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ
Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé
Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.