ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ | ÌGBÉYÀWÓ Ẹ Máa Fìfẹ́ Hàn Sí Ara Yín TẸ̀ Ẹ̣́ Ẹ Máa Fìfẹ́ Hàn Sí Ara Yín Tí tọkọtaya bá nífẹ̀ẹ́ ara wọn tí wọ́n sì ń ṣìkẹ́ ara wọn, ilé wọn máa tòrò. Máà bínú, ètò tó o fi ń wo fídíò kò ṣiṣẹ́. Wa Fídíò Yìí Jáde Àwọn Àkòrí Tó Jọ Ọ́ Ìgbéyàwó Ìgbéyàwó àti Ìdílé O Tún Lè Wo ÌGBÉYÀWÓ ÀTI ÌDÍLÉ Bí Ẹ Ṣe Lè Máa Fìfẹ́ Hàn Síra Yín Báwo ni tọkọtaya ṣe lè fi hàn pé àwọn nífẹ̀ẹ́ ara àwọn dénú? Wo àbá mẹ́rin tó dá lórí àwọn ìlànà tó wà nínú Bíbélì. ÌGBÉYÀWÓ ÀTI ÌDÍLÉ Tọkọtaya Aláyọ̀: Ẹ Máa Bọ̀wọ̀ Fúnra Yín Bíbélì máa jẹ́ kẹ́ ẹ túbọ̀ máa bọ̀wọ̀ fún ara yín tó bá jẹ́ pé ẹ kì í ṣe bẹ́ẹ̀ tẹ́lẹ̀. OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ Ǹjẹ́ Bíbélì Lè Ràn Mí Lọ́wọ́ Láti Ní Ìdílé Aláyọ̀? Ìmọ̀ràn ọlọ́gbọ́n láti inú Bíbélì ti ran ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn lọ́kùnrin àti lóbìnrin lọ́wọ́ láti ní ìdílé aláyọ̀. ÌGBÉYÀWÓ ÀTI ÌDÍLÉ Ẹ Máa Wáyè fún Ara Yín Tọkọtaya lè wà nínú yàrá kan náà síbẹ̀ kí wọ́n má máa bára wọn sọ̀rọ̀. Báwo ni tọkọtaya ṣe lè máa lo àkókò tí wọ́n bá fi wà pa pọ̀ lọ́nà tó dára jù lọ? Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Ẹ Máa Fìfẹ́ Hàn Sí Ara Yín ÌGBÉYÀWÓ ÀTI ÌDÍLÉ Ẹ Máa Fìfẹ́ Hàn Sí Ara Yín Yorùbá Ẹ Máa Fìfẹ́ Hàn Sí Ara Yín https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/500300115/univ/art/500300115_univ_sqr_xl.jpg ijwhf àpilẹ̀kọ 29