Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ‘Ẹ Máa Kéde Ìhìn Rere!’ Ọdún 2024
Friday
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ ọjọ́ Friday dá lórí Lúùkù 2:10—‘Ìhìn rere ayọ̀ ńláǹlà, èyí tí gbogbo èèyàn máa ní.’
Saturday
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ ọjọ́ Saturday dá lórí Sáàmù 96:2—“Ẹ máa kéde ìhìn rere ìgbàlà rẹ̀ láti ọjọ́ dé ọjọ́.”
Sunday
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ ọjọ́ Sunday dá lórí Mátíù 24:14—“. . . nígbà náà ni òpin yóò dé.”
Ohun Tá A Fẹ́ Kí Àwọn Tó Wá Sí Àpéjọ Yìí Mọ̀
Ohun tá a fẹ́ kí àwọn tó wá sí àpéjọ yìí mọ̀.
O Tún Lè Wo
NÍPA WA
Lọ Sí Àpéjọ tọdún 2024—‘Ẹ Máa Kéde Ìhìn Rere!’
A fẹ́ kó o wá sí àpéjọ ọlọ́jọ́ mẹ́ta táwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ṣe.
ÀPÉJỌ
A Fẹ́ Kó O Wá: Àpéjọ Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti 2024, ‘Ẹ Máa Kéde Ìhìn Rere!’
A pè ẹ́ wá sí àpéjọ ọlọ́jọ́ mẹ́ta tí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ṣe.
ÀPÉJỌ
Ìtọ́wò Fídíò Ìtàn Bíbélì: Ìmọ́lẹ̀ Tòótọ́ fún Aráyé
Wo ìtọ́wò abala kìíní fídíò Ìhìn Rere Látọ̀dọ̀ Jésù. A máa wo abala yìí ní àpéjọ agbègbè àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà tọdún 2024.