Sùúrù
Báwo ni Jèhófà ṣe fi hàn pé òun ní sùúrù?
Tún wo Ne 9:30
-
Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:
-
Jer 7:23-25—Jèhófà jẹ́ ká mọ ìgbà tóun ti ń fara dà á bọ̀ fáwọn èèyàn òun tí wọ́n ya aláìgbọràn
-
2Pe 3:3-9, 15—Àpọ́sítélì Pétérù sọ bí sùúrù Jèhófà ṣe pọ̀ tó àti ìdí tó fi máa ń ní sùúrù, àmọ́ ó sọ pé sùúrù Jèhófà máa dópin lọ́jọ́ kan
-
Kí nìdí tó fi yẹ ká kọ́ bá a ṣe lè máa ní sùúrù?
Owe 25:15; Ef 4:1-3; 2Ti 2:24, 25; 4:2
-
Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:
-
Jẹ 39:19-21; 40:14, 15, 23; 41:1, 9-14 —Bó tiẹ̀ jẹ́ pé wọ́n ta Jósẹ́fù sóko ẹrú ní Íjíbítì, tí wọ́n hùwà àìdáa sí i, tí wọ́n sì fi í sẹ́wọ̀n fọ́pọ̀ ọdún, ó ní sùúrù, ó ń fara dà á, ìyẹn sì jẹ́ kí ìgbàgbọ́ ẹ̀ túbọ̀ lágbára
-
Heb 6:10-15—Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù fi àpẹẹrẹ Àbúráhámù kọ́ àwa Kristẹni pé ó ṣe pàtàkì ká máa ní sùúrù
-