Àwòrán Ìṣekúṣe
Job 31:1; Sm 101:2, 3; Mt 5:27-30; Kol 3:5
Tún wo 1Kọ 6:18; Ef 4:17-19
Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:
Jẹ 6:1, 2; Jud 6—Àwọn áńgẹ́lì kan tẹjú mọ́ àwọn obìnrin débi tó fi wù wọ́n láti bá wọn ṣèṣekúṣe, ìyẹn sì mú kí àjọṣe wọn pẹ̀lú Jèhófà bà jẹ́
2Sa 11:2-4—Torí pé Ọba Dáfídì tẹjú mọ́ Bátí-ṣébà nígba tó ń wẹ̀, ó bá a ṣèṣekúṣe, ó sì tún pa ọkọ ẹ̀ nígbà tó yá