Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2018-2019​—Tí Alábòójútó Àyíká Máa Bá Wa Ṣe

Wo ìtòlẹ́sẹẹsẹ àpéjọ àyíká yìí, kó o sì máa fọkàn bá àpéjọ àyíká yìí lọ. Àkòrí àpéjọ yìí ni “Má Ṣojo!”

Má Ṣojo!

Kí ló lè mú kó ṣòro láti jẹ́ aláìṣojo, kí ló sì lè mú ká ní ànímọ́ yìí?

Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí

A máa sọ̀rọ̀ nípa àwọn ìbéèrè yìí, a sì máa dáhùn wọn nígbà tí ìtòlẹ́sẹẹsẹ àpéjọ náà bá ń lọ lọ́wọ́.