Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2018-2019—Tí Aṣojú Ẹ̀ka Ọ́fí ìsì Máa Bá Wa Ṣe
Wo ìtòlẹ́sẹẹsẹ àpéjọ àyíká yìí, a máa gbọ́ àsọyé látẹnu aṣojú ẹ̀ka ọ́fí ìsì.
Jẹ́ Alágbára!
Ìpàdé yìí máa jẹ́ ká mọ bá a ṣe lè ní okun táá jẹ́ ká lè dúró gbọin nínú ìgbàgbọ́.
Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí
A máa dáhùn àwọn ìbéèrè yìí nígbà tí àpéjọ náà bá ń lọ lọ́wọ́.