ILÉ ÌṢỌ́ July 2015 | Bó O Ṣe Lè Borí Àníyàn

Ẹgbẹẹgbẹ̀rún èèyàn ló ń dojú kọ àjálù àtàwọn ìṣòro míì, àmọ́ àwọn kan kì í fi bẹ́ẹ̀ kó ọ̀kan sókè bíi ti àwọn míì. Báwo ni wọ́n ṣe ń ṣé e?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Gbogbo Èèyàn Ló Ń Ṣàníyàn!

Ìwádìí fi hàn pé àníyàn tí kò tó nǹkan pàápàá lè mú kéèyàn kú ní rèwerèwe. Báwo lo ṣe lè borí àníyàn?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Àníyàn Nípa Owó

Ọkùnrin kan pèsè fún ìdílé rẹ̀ nígbà tí owó ọjà di ọ̀wọ́n gógó.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Àníyàn Nípa Ìdílé

Ìtàn bí ọkọ obìnrin kan ṣe já a jù sílẹ̀ àti bí obìnrin náà ṣe borí ìṣòrò jẹ́ ká mọ ohun tí ìgbàgbọ́ gidi jẹ́.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Àníyàn Nípa Ewu

Kí lo lè ṣe tí o kò fi ní máa páyà nípa ogun, ìwà ọ̀daràn, ìbàlújẹ́, ìyípadà ojú ọjọ́, àti àjàkálẹ̀ àrùn?

BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ

Ìwà Burúkú Ọwọ́ Mi Ń Peléke Sí I

Oníjàgídíjàgan èèyàn ni Stephen McDowell, àmọ́ bí kó ṣe sí níbi tí àwọn ọ̀rẹ́ ti lu èèyàn pa mú kó yí ìgbésí ayé rẹ̀ pa dà.

Ǹjẹ́ A Lè Mú Inú Ọlọ́run Dùn?

A lè rí ìdáhùn nínú bí Jóòbù, Lọ́ọ̀tì àti Dáfídì ṣe gbé ìgbé ayé wọn, àwọn mẹ́tẹ̀ẹ̀ta ló ṣe àṣìṣe ńlá.

Ǹjẹ́ O Mọ̀?

Báwo ni wọ́n ṣe ń lo ọlọ ọlọ́wọ́ láyé àtijọ́? Kí ló túmọ̀ sí láti wà ní “ipò oókan àyà?”

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Ǹjẹ́ ìwà ibi máa dópin?

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Ǹjẹ́ Ọlọ́run Á Gbọ́ Mi Tí Mo Bá Gbàdúrà?

Ṣé Ọlọ́run bìkítà nípa àwọn ìṣòro wa?