ILÉ ÌṢỌ́ February 2015 | Bi O Se Le Gbadun Ise Re

Opo eeyan lo gbadun ise ti won n se, o si n mere wa. Ki lo ti ran won lowo lati ni emi to daa si sise ise asekara?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ise Asekara—Se O si Niyi Lode Oni?

Awon kan ro pe ise asekara bu awon ku. Amo opo eeyan lo n gbadun ise asekara. Ki lo mu ki won gbadun ise won?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Bi O Se Le Gbadun Ise Asekara

Je ka wo awon imoran to gbese ti Bibeli fun lori ba a se le gbadun ise asekara ka si fi okan bale.

ÌJÍRÒRÒ LÁÀÁRÍN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ ÀTI ẸNÌ KAN

Ki Nidi To Fi Ye Ka Maa Sayewo Bibeli?

Bo tile je pe won ti ko Bibeli tipe, awon imoran re si wulo lonii. Bawo ni awon ilana Bibeli se le ran e lowo nigbeesi aye?

BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ

Awon Idahun Taara Ti Mo Ri Ninu Bibeli Wu Mi Lori Gan-an

Ernest Loedi ri idahun si awon ibeere pataki nigbeesi aye. Awon idahun to se taara ti Bibeli fun un mu ko ni ireti nipa ojo ola.

TẸ̀ LÉ ÀPẸẸRẸ ÌGBÀGBỌ́ WỌN

“Itumo Ko Ha Je Ti Olorun?”

Ki lo ran Josefu lati fi igboya tumo ala olori agboti ati olori oluse buredi ati Farao? Bawo ni Josefu se jade lewon to si di eni nla laaarin ojo kan soso?

Ohun Ti Bibeli So

Foju inu wo alaafia ti ijoba kan soso kari aye maa mu wa. Ki nidi ta a fi le gba gbo pe Olorun maa mu ileri to se nipa ijoba naa se? Ta lo maa je oba ijoba naa?

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Ṣé Ọgbọ́n Èèyàn Ni Wọ́n Fi Kọ Bíbélì?

Gbọ́ ohun tí Bíbélì fúnra rẹ̀ sọ.