ILÉ ÌṢỌ́ August 2014 | Ǹjẹ́ Ọlọ́run Bìkítà Nípa Rẹ?
Báwo ni Ọlọ́run ṣe ń fi hàn pé òun bìkítà nípa wa?
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Ọlọ́run Máa Ń Bójú Tó Ẹ
Kí nìdí tí Bíbélì fi pé Jèhófà ni ‘Ọlọ́run tó rí ohun gbogbo’?
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Ọlọ́run Ń Tù Ẹ́ Nínú
Tí ìṣòro rẹ bá rí bíńtín lẹ́gbẹ̀ẹ́ ti ọ̀kẹ́ àìmọye àwọn èèyàn tí ìṣòro wọn gadabú ńkọ́?
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Ọlọ́run Fẹ́ Kí O Sún Mọ́ Òun
Tó bá jẹ́ pé o gba Ọlọ́run gbọ́ àmọ́ tó ń ṣe ẹ́ bíi pé o jìnnà sí i ńkọ́?
BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ
Mo Fẹ́ Gba Àwọn Èèyàn Lọ́wọ́ Ìwà Ìrẹ́jẹ àti Ìwà Ipá
Antoine Touma gbóná nínú ìjà Kọnfú, àmọ́ Ìwé 1 Tímótì 4:8 tún ayé rẹ̀ ṣe.
TẸ̀ LÉ ÀPẸẸRẸ ÌGBÀGBỌ́ WỌN
“Ẹ jọ̀wọ́, Ẹ Fetí Sí Àlá Tí Mo Lá”
Wàhálà tó wà nínú ìdílé Jósẹ́fù jẹ́ ẹ̀kọ́ fáwọn ìdílé tó tún ìgbéyàwó ṣe.
ÀWỌN ÒǸKÀWÉ WA BÉÈRÈ PÉ
Ta Ló Dá Ọlọ́run?
Ṣé ó bọ́gbọ́n mu kéèyàn gbà pé kò sígbà tí Ọlọ́run kò sí?
Ohun Tí Bíbélì Sọ
Ṣé òótọ́ ni pé ọ̀pọ̀ ìsìn ò ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run?
Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì
Ṣé Ẹni Gidi Ni Ọlọ́run?
Bíbélì sọ pé Ọlọ́run lo agbára rẹ̀ láti dá ohun gbogbo, àmọ́ ṣe ó tiẹ̀ bìkítà nípa wa?