ILÉ ÌṢỌ́ May 2014 | Ta Ló Mọ Ọjọ́ Ọ̀la?

Ìdáhùn ìbéèrè yìí lè tún ayé rẹ ṣe.

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Àsọtẹ́lẹ̀ Tó ti Ṣẹ àti Àìmọye Tí Kò Ṣẹ

Ta ló ti sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa ọjọ́ ọ̀la rí tó sì ṣẹ?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ta Ló Mọ Ọjọ́ Ọ̀la?

Àsọtẹ́lẹ̀ kan ti wà nípa ọjọ́ ọ̀la tó ṣe é gbára lé.

ÌJÍRÒRÒ LÁÀÁRÍN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ ÀTI ẸNÌ KAN

Ǹjẹ́ Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Gbà Jésù Gbọ́?

Tí wọ́n bá gba Jésù gbọ́, kí nìdí tí wọn ò fi pe ara wọn ní Ẹlẹ́rìí Jésù?

Ǹjẹ́ O Mọ̀?

Kí nìdí tí àwọn Júù fi sọ fún Pílátù pé kó ṣẹ́ ẹsẹ̀ Jésù? Ṣé Dáfídì tiẹ̀ lè fi kànnàkànnà lásán pa Gòláyátì?

TẸ̀ LÉ ÀPẸẸRẸ ÌGBÀGBỌ́ WỌN

Ó Fara Da Ọgbẹ́ Ọkàn

Àpẹẹrẹ ìgbàgbọ́ Màríà ìyá Jésù lè ràn wá lọ́wọ́ nígbà tí àwa náà bá dojú kọ ìbànújẹ́ tó fẹ́ dà bí “idà oró.”

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Tó bá jẹ́ pé Ọlọ́run ló ń ṣàkóso ayé kí ló dé tí ìyà fi pọ̀ gan-an láyé?

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Ṣé Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run ni Bíbélì Ti Wá?

Ọ̀pọ̀ àwọn tó kọ Bíbélì sọ pé Ọlọ́run ló darí àwọn láti kọ́ ohun táwọn kọ. Kí nìdí?