Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Àwọn nǹkan mẹ́ta wo ni Ọlọ́run ti ṣe láti gba aráyé lọ́wọ́ ìjìyà? WO OJÚ ÌWÉ 5 ÀTI 6.

Àwọn nǹkan wo lo lè ṣe tó o fi lè tu ẹni tí ọkọ tàbí aya rẹ̀ kú nínú? WO OJÚ ÌWÉ 10 SÍ 12.

Kí nìdí tó fi yẹ kí àwọn ọmọlẹ́yìn Kristi wàásù fún àwọn èèyàn? WO OJÚ ÌWÉ 17.

Kí ni nǹkan tó o lè ṣe láti ran ọmọ rẹ lọ́wọ́ kó lè di àgbà tó dáńgájíá? WO OJÚ ÌWÉ 19.

Kí ló mú kí ọkùnrin kan tó kórìíra ìsìn àti àwọn aláṣẹ ìjọba di ẹni tó ń wàásù ọ̀rọ̀ Ọlọ́run? WO OJÚ ÌWÉ 28 ÀTI 29.