ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ November 2023
Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti January 8–February 4, 2024 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 46
Jèhófà Fi Dá Wa Lójú Pé Òun Máa Sọ Ayé Di Párádísè
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní January 8-14, 2024.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 47
Bá A Ṣe Lè Mú Kí Ìfẹ́ Tá A Ní Sáwọn Ará Túbọ̀ Lágbára
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní January 15-21, 2024.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 48
Jẹ́ Kó Túbọ̀ Dá Ẹ Lójú Pé Jèhófà Máa Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Nígbà Ìṣòro
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní January 22-28, 2024.
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 49
Ṣé Jèhófà Máa Dáhùn Àdúrà Mi?
A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní January 29–February 4, 2024.
Ọwọ́ Hulda Tẹ Ohun Tó Ń Wá
Báwo ni Hulda ṣe rówó ra tablet tó fi ń wàásù, tó sì fi ń ṣèpàdé?