JÍ! July 2015 | Ohun Márùn-Ún Tó Máa Mú Kí Ìlera Rẹ Dára Sí I
O lè ṣe ohun tó máa dín àìsàn kù tàbí ohun tí kò ní jẹ kó o ṣe àìsàn rárá.
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Ohun Tó Máa Mú Kí Ìlera Rẹ Dára Sí I
Ohun márùn-ún tó o lè ṣe báyìí kí ìlera rẹ lè dára sí i
ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ
Bó O Ṣe Lè Kọ́ Ọmọ Rẹ Láti Máa Gbọ́ràn
Tó bá ṣẹlẹ̀ pé gbogbo ìgbà ni ọmọ rẹ máa ń kọ ọ̀rọ̀ sí ẹ lẹ́nu, kí lo lè ṣe? Ohun márùn-ún wà tó lè ràn ẹ́ lọ́wọ́.
OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ
Ìwà Ipa
Irú ojú wo ni Ọlọ́run fi ń wo àwọn oníwà ipá? Ṣé àwọn oníwà ipa lè yíwà pa dà?
ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ
Bí Ìfẹ́ Yín Ṣe Lè Jinlẹ̀ Sí I
Ṣé ìfẹ́ tó o ní fún ọkọ tàbí aya rẹ mú kí ìdílé yín dúró sán-ún?
OHUN TÓ Ń LỌ LÁYÉ
Nípa Àyíká
Àwọn ìròyìn lọ́ọ́lọ́ọ́ ń gbé ìbéèrè náà dìde pé, “Kí ló dé táwọn èèyàn ò fi rí nǹkan kan ṣe sọ́rọ̀ àyíká tó ń bà jẹ́?”
Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì
Olè Ò Dáa
Ojú wo ni Ọlọ́run fi ń wo olè jíjà? Ka Ẹkísódù 20:15. Wo fídíò yìí kí ìwọ àti Kọ́lá jọ kẹ́kọ̀ọ́ sí i.