JÍ! May 2015

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Nje O Gba Pe Olorun Wa? To O Ba Gba Anfaani Wo Lo Maa Se E?

Se idahun ibeere ti opo eeyan ko ka si wulo fun wa?

OHUN TÓ Ń LỌ LÁYÉ

Ohun To N Sele Nile Afirika

Isoro abetele ti a o so ati pipa eranko raino fara pe ara won.

ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ

Bo O Se Le Ni Ajose To Daa Pelu Awon Ana Re

Ohun meta ti ko ni je ki isoro to o ni pelu awon ana re da wahala sile laarin iwo ati oko tabi iyawo re.

OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ

Tete Tita

Se ere owo lasan ni?

ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ

Ohun To O Le Se To Ba N Se E Bi I Pe O Ko Ni Ore

Ti inu re ba n baje tori pe o ko loree, nse lo maa n da aisan si e lara, o maa dabi eni to n mu siga meedogun lojumo. Ki lo le se ko ma baa maa se e bi i pe won pa e ti tabi pe o ko loree?

OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ

Awon Eranko

Bawo lo se ye ka maa se awon eranko?

TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?

Ise Ti Irun Imu Ologbo N Se

Ki nidi ti awon onimo sayensi fi n se robooti ti won pe ni e-whiskers?

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Kí Ló Máa Ń Ṣẹlẹ̀ Nínú Gbọ̀ngàn Ìjọba?

Wo bó ṣe máa ń rí tá a bá wà nínú Gbọ̀ngàn Ìjọba.

Ẹ Jọ̀ọ́ àti Ẹ Ṣeun

Kọ́lá ti wá rí i pé ó dára kí òun máa sọ pé ẹ jọ̀ọ́ àti ẹ ṣeun.