B15
Kàlẹ́ńdà Àwọn Hébérù
NÍSÀN (ÁBÍBÙ) March—April |
14 Ìrékọjá 15-21 Búrẹ́dì Aláìwú 16 Fífi àwọn àkọ́so ṣe ọrẹ |
Òjò àti yìnyín tó yọ́ mú kí odò Jọ́dánì kún sí i |
Ọkà Báálì |
ÍÍYÀ (SÍFÌ) April—May |
14 Ìrékọjá lẹ́yìn àkókò rẹ̀ |
Ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn bẹ̀rẹ̀, kì í sí kùrukùru |
Àlìkámà |
SÍFÁNÌ May—June |
6 Àjọyọ̀ Àwọn Ọ̀sẹ̀ (Pẹ́ńtíkọ́sì) |
Ooru ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn, ojú ọjọ́ mọ́ kedere |
Àlìkámà, àkọ́pọ́n èso ọ̀pọ̀tọ́ |
TÁMÚSÌ June—July |
Ooru pọ̀ sí i, ìrì púpọ̀ máa ń sẹ̀ ní agbègbè yìí |
Àkọ́pọ́n èso àjàrà |
|
ÁBÌ July—August |
Ìgbà tí ooru mú jù lọ |
Àwọn èso ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn |
|
ÉLÚLÌ August—September |
Ooru ṣì wà |
Èso déètì, ọ̀pọ̀tọ́ àti àjàrà |
|
TÍṢÍRÌ (ÉTÁNÍMÙ) September—October |
1 Fífun kàkàkí 10 Ọjọ́ Ètùtù 15-21 Àjọyọ̀ Àtíbàbà 22 Àpéjọ ọlọ́wọ̀ |
Ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn parí, òjò àkọ́rọ̀ bẹ̀rẹ̀ |
Títúlẹ̀ |
HÉṢÍFÁNÙ (BÚLÌ) October—November |
Òjò winniwinni |
Èso ólífì |
|
KÍSÍLÉFÌ November—December |
25 Àjọyọ̀ Ìyàsímímọ́ |
Òjò ń pọ̀ sí i, ìrì dídì, yìnyín bo òkè |
Agbo ẹran kò sí níta mọ́ |
TÉBÉTÌ December—January |
Ìgbà tí òtútù mú jù lọ, ìgbà òjò, yìnyín bo òkè |
Ohun ọ̀gbìn ń hù |
|
ṢÉBÁTÌ January—February |
Òtútù ò fi bẹ́ẹ̀ mú mọ́, òjò ṣì ń rọ̀ |
Álímọ́ńdì yọ ìtànná |
|
ÁDÁRÌ February—March |
14, 15 Púrímù |
Ààrá ń sán lemọ́lemọ́, yìnyín sì ń já bọ́ |
Ọ̀gbọ̀ |
FÍÁDÀ March |
Ìgbà méje ni wọ́n máa ń ní oṣù kẹtàlá láàárín ọdún 19 |