Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Dáfídì Fi Sùúrù Dúró De Jèhófà

Wàá rí bí Dáfídì ṣe fi sùúrù dúró de Jèhófà nígbà tí wọ́n hùwà àìdáa sí i. Ìtàn náà dá lórí 1 Sámúẹ́lì 24:2-15; 25:1-35; 26:2-12; Sáàmù 37:1-7

O Tún Lè Wo

ÀWỌN Ẹ̀KỌ́ TÓ O LÈ KỌ́ LÁTINÚ BÍBÉLÌ

Dáfídì àti Sọ́ọ̀lù

Kí nìdí tí ọ̀kan nínú àwọn ọkùnrin yìí fi kórìíra ìkejì, báwo ni ìkejì yìí ṣe hùwà sí èyí tó kórìíra rẹ̀?

TẸ̀ LÉ ÀPẸẸRẸ ÌGBÀGBỌ́ WỌN

Ábígẹ́lì Hùwà Ọlọgbọ́n

Kí la rí kọ́ látinú bí ilé ọkọ kò ṣe rọrùn fún Ábígẹ́lì?