Àwọn Ohun Àgbàyanu Tó Máa Ṣẹlẹ̀ Lọ́jọ́ Ọ̀la
Wàá rí ohun tí Bíbélì pè ní “ìyè tòótọ́,” ìyẹn ìgbà tí Ọlọ́run máa mú àwọn ìlérí ẹ̀ ṣẹ, táá sì tẹ́ ìfẹ́ gbogbo ohun alààyè lọ́rùn. (1 Tímótì 6:19; Sáàmù 145:16) Ṣé o rò pé àwọn nǹkan tá a sọ yìí máa ṣẹlẹ̀?