YAN Ọ̀KAN Ìwé Bíbélì Jẹ́nẹ́sísì Ẹ́kísódù Léfítíkù Nọ́ńbà Diutarónómì Jóṣúà Àwọn Onídàájọ́ Rúùtù 1 Sámúẹ́lì 2 Sámúẹ́lì 1 Àwọn Ọba 2 Àwọn Ọba 1 Kíróníkà 2 Kíróníkà Ẹ́sírà Nehemáyà Ẹ́sítà Jóòbù Sáàmù Òwe Oníwàásù Orin Sólómọ́nì Àìsáyà Jeremáyà Ìdárò Ìsíkíẹ́lì Dáníẹ́lì Hósíà Jóẹ́lì Émọ́sì Ọbadáyà Jónà Míkà Náhúmù Hábákúkù Sefanáyà Hágáì Sekaráyà Málákì Mátíù Máàkù Lúùkù Jòhánù Ìṣe Róòmù 1 Kọ́ríńtì 2 Kọ́ríńtì Gálátíà Éfésù Fílípì Kólósè 1 Tẹsalóníkà 2 Tẹsalóníkà 1 Tímótì 2 Tímótì Títù Fílémónì Hébérù Jémíìsì 1 Pétérù 2 Pétérù 1 Jòhánù 2 Jòhánù 3 Jòhánù Júùdù Ìfihàn Orí 1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 Ìwé Oníwàásù Orí 1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí 1 Asán ni ohun gbogbo (1-11) Ayé wà títí láé (4) Àwọn ohun tó ń yí po ní ayé (5-7) Kò sí ohun tuntun lábẹ́ oòrùn (9) Ó níbi tí ọgbọ́n èèyàn mọ (12-18) Ìmúlẹ̀mófo (14) 2 Àgbéyẹ̀wò àwọn ohun tí Sólómọ́nì ṣe (1-11) Ó níbi tí ọgbọ́n èèyàn wúlò dé (12-16) Asán tó wà nínú iṣẹ́ àṣekára (17-23) Máa jẹ, máa mu, kí o sì gbádùn iṣẹ́ rẹ (24-26) 3 Ohun gbogbo ni àkókò wà fún (1-8) Ká gbádùn ayé, ẹ̀bùn Ọlọ́run ni (9-15) Ayérayé wà ní ọkàn èèyàn (11) Òdodo ni Ọlọ́run fi ń ṣe ìdájọ́ gbogbo èèyàn (16, 17) Bí èèyàn ṣe ń kú náà ni ẹranko ń kú (18-22) Gbogbo wọn á pa dà sí erùpẹ̀ (20) 4 Ìnilára burú ju ikú lọ (1-3) Ojú tó yẹ ká fi wo iṣẹ́ (4-6) Iyì ọ̀rẹ́ (7-12) Ẹni méjì sàn ju ẹnì kan lọ (9) Ìgbésí ayé alákòóso lè jẹ́ asán (13-16) 5 Wá síwájú Ọlọ́run pẹ̀lú ìbẹ̀rù tó yẹ (1-7) Àwọn tó ga ju àwọn tó wà nípò gíga ń ṣọ́ wọn (8, 9) Asán tó wà nínú ọrọ̀ (10-20) Owó kì í tó ẹni tó bá nífẹ̀ẹ́ owó (10) Oorun òṣìṣẹ́ máa ń dùn (12) 6 Ọ̀pọ̀ ohun ìní láìsí ìgbádùn (1-6) Gbádùn ohun tí o ní nísinsìnyí (7-12) 7 Orúkọ rere àti ọjọ́ ikú (1-4) Ìbáwí tí ọlọ́gbọ́n fúnni (5-7) Òpin nǹkan sàn ju ìbẹ̀rẹ̀ rẹ̀ lọ (8-10) Àǹfààní ọgbọ́n (11, 12) Ọjọ́ rere àti ọjọ́ burúkú (13-15) Yẹra fún àṣejù (16-22) Àwọn ohun tí akónijọ kíyè sí (23-29) 8 Lábẹ́ àkóso èèyàn aláìpé (1-17) Pa àṣẹ ọba mọ́ (2-4) Ìjọba èèyàn ń pani lára (9) Nígbà tí a kò bá tètè mú ìdájọ́ ṣẹ (11) Máa jẹ, máa mu, kí o sì máa yọ̀ (15) 9 Ohun kan náà ló ń gbẹ̀yìn gbogbo wọn (1-3) Gbádùn ayé rẹ bí ikú tiẹ̀ máa dé (4-12) Àwọn òkú ò mọ nǹkan kan (5) Èèyàn ò lè ṣe nǹkan kan nínú Isà Òkú (10) Ìgbà àti èèṣì (11) Kì í ṣe gbogbo ìgbà ni àwọn èèyàn máa ń mọyì ọgbọ́n (13-18) 10 Ìwà òmùgọ̀ díẹ̀ ń ba ọgbọ́n jẹ́ (1) Ewu tó wà nínú àìmọṣẹ́ (2-11) Ohun búburú tó máa ń ṣẹlẹ̀ sí àwọn òmùgọ̀ (12-15) Ìwà òmùgọ̀ àwọn alákòóso (16-20) Ẹyẹ lè tún ọ̀rọ̀ rẹ sọ (20) 11 Lo àǹfààní tí o ní (1-8) Fọ́n oúnjẹ rẹ sí ojú omi (1) Fún irúgbìn láti àárọ̀ títí di ìrọ̀lẹ́ (6) Gbádùn ìgbà ọ̀dọ́ lọ́nà tó yẹ (9, 10) 12 Rántí Ẹlẹ́dàá kí ọjọ́ ogbó tó dé (1-8) Ìparí ọ̀rọ̀ akónijọ (9-14) Ọ̀rọ̀ ọlọ́gbọ́n dà bí ọ̀pá kẹ́sẹ́ màlúù (11) Bẹ̀rù Ọlọ́run tòótọ́ (13) Pa Dà Èyí Tó Kàn Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Oníwàásù—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí BÍBÉLÌ MÍMỌ́ TI ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN (TÍ A TÚN ṢE LỌ́DÚN 2018) Oníwàásù—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Yorùbá Oníwàásù—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1001061100/univ/wpub/1001061100_univ_sqr_xl.jpg nwt Oníwàásù ojú ìwé 910-911