YAN Ọ̀KAN Ìwé Bíbélì Jẹ́nẹ́sísì Ẹ́kísódù Léfítíkù Nọ́ńbà Diutarónómì Jóṣúà Àwọn Onídàájọ́ Rúùtù 1 Sámúẹ́lì 2 Sámúẹ́lì 1 Àwọn Ọba 2 Àwọn Ọba 1 Kíróníkà 2 Kíróníkà Ẹ́sírà Nehemáyà Ẹ́sítà Jóòbù Sáàmù Òwe Oníwàásù Orin Sólómọ́nì Àìsáyà Jeremáyà Ìdárò Ìsíkíẹ́lì Dáníẹ́lì Hósíà Jóẹ́lì Émọ́sì Ọbadáyà Jónà Míkà Náhúmù Hábákúkù Sefanáyà Hágáì Sekaráyà Málákì Mátíù Máàkù Lúùkù Jòhánù Ìṣe Róòmù 1 Kọ́ríńtì 2 Kọ́ríńtì Gálátíà Éfésù Fílípì Kólósè 1 Tẹsalóníkà 2 Tẹsalóníkà 1 Tímótì 2 Tímótì Títù Fílémónì Hébérù Jémíìsì 1 Pétérù 2 Pétérù 1 Jòhánù 2 Jòhánù 3 Jòhánù Júùdù Ìfihàn Orí 1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 14 Ìwé Hósíà Orí 1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 14 Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí 1 Ìyàwó Hósíà àti àwọn ọmọ tó bí (1-9) Jésírẹ́lì (4), Lo-ruhámà (6), àti Lo-ámì (9) Ìmúbọ̀sípò àti ìṣọ̀kan ń bọ̀ (10, 11) 2 Ọlọ́run fìyà jẹ Ísírẹ́lì aláìṣòótọ́ (1-13) Ó pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà ọkọ rẹ̀ (14-23) “Ọkọ Mi ni wàá máa pè mí” (16) 3 Hósíà gba ìyàwó rẹ̀ alágbèrè pa dà (1-3) Ísírẹ́lì máa pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà (4, 5) 4 Jèhófà pe Ísírẹ́lì lẹ́jọ́ (1-8) Kò sí ìmọ̀ Ọlọ́run ní ilẹ̀ náà (1) Ísírẹ́lì bọ̀rìṣà, ó sì ṣe ìṣekúṣe (9-19) Ẹ̀mí ìṣekúṣe mú kí wọ́n ṣìnà (12) 5 Éfúrémù àti Júdà gba ìdájọ́ (1-15) 6 Ẹ jẹ́ ká pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà (1-3) Ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ tí àwọn èèyàn náà ní tètè ń pòórá (4-6) Ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ sàn ju ẹbọ lọ (6) Ìwà àìnítìjú tí àwọn èèyàn náà hù (7-11) 7 Àpèjúwe nípa ìwà ibi Éfúrémù (1-16) Kò sí ọ̀nà àbáyọ nínú àwọ̀n Ọlọ́run (12) 8 Wọ́n jìyà torí pé wọ́n bọ̀rìṣà (1-14) Wọ́n gbin afẹ́fẹ́, wọ́n sì ká ìjì (7) Ísírẹ́lì ti gbàgbé Ẹni tó dá a (14) 9 Ẹ̀ṣẹ̀ Éfúrémù mú kí Ọlọ́run kọ̀ ọ́ (1-17) Wọ́n fi ara wọn fún ọlọ́run tó ń tini lójú (10) 10 Ísírẹ́lì jẹ́ igi àjàrà tí kò dáa, ó máa pa run (1-15) Fífúnrúgbìn àti kíkórè (12, 13) 11 Ìfẹ́ tí Ọlọ́run ní sí Ísírẹ́lì láti ìgbà tó wà lọ́mọdé (1-12) ‘Láti Íjíbítì ni mo ti pe ọmọkùnrin mi’ (1) 12 Éfúrémù ní láti pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà (1-14) Jékọ́bù bá Ọlọ́run jà (3) Jékọ́bù sunkún kó lè rí ojú rere Ọlọ́run (4) 13 Éfúrémù abọ̀rìṣà gbàgbé Jèhófà (1-16) “Ìwọ Ikú, oró rẹ dà?” (14) 14 Hósíà bẹ̀ wọ́n pé kí wọ́n pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà (1-3) Ẹ fi ètè rú ẹbọ ìyìn (2) Ísírẹ́lì aláìṣòótọ́ máa gba ìwòsàn (4-9) Pa Dà Èyí Tó Kàn Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Hósíà—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí BÍBÉLÌ MÍMỌ́ TI ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN (TÍ A TÚN ṢE LỌ́DÚN 2018) Hósíà—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Yorùbá Hósíà—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1001061100/univ/wpub/1001061100_univ_sqr_xl.jpg nwt Hóséà ojú ìwé 1221