YAN Ọ̀KAN Ìwé Bíbélì Jẹ́nẹ́sísì Ẹ́kísódù Léfítíkù Nọ́ńbà Diutarónómì Jóṣúà Àwọn Onídàájọ́ Rúùtù 1 Sámúẹ́lì 2 Sámúẹ́lì 1 Àwọn Ọba 2 Àwọn Ọba 1 Kíróníkà 2 Kíróníkà Ẹ́sírà Nehemáyà Ẹ́sítà Jóòbù Sáàmù Òwe Oníwàásù Orin Sólómọ́nì Àìsáyà Jeremáyà Ìdárò Ìsíkíẹ́lì Dáníẹ́lì Hósíà Jóẹ́lì Émọ́sì Ọbadáyà Jónà Míkà Náhúmù Hábákúkù Sefanáyà Hágáì Sekaráyà Málákì Mátíù Máàkù Lúùkù Jòhánù Ìṣe Róòmù 1 Kọ́ríńtì 2 Kọ́ríńtì Gálátíà Éfésù Fílípì Kólósè 1 Tẹsalóníkà 2 Tẹsalóníkà 1 Tímótì 2 Tímótì Títù Fílémónì Hébérù Jémíìsì 1 Pétérù 2 Pétérù 1 Jòhánù 2 Jòhánù 3 Jòhánù Júùdù Ìfihàn Orí 1 2 3 Ìwé Hábákúkù Orí 1 2 3 Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí 1 Wòlíì náà ké pe Jèhófà pé kó ran òun lọ́wọ́ (1-4) “Jèhófà, báwo ló ṣe máa pẹ́ tó?” (2) ‘Kí nìdí tí o fi fàyè gba ìnilára?’ (3) Ọlọ́run lo àwọn ará Kálídíà láti ṣèdájọ́ (5-11) Wòlíì náà bẹ Jèhófà (12-17) ‘Ọlọ́run mi, ìwọ kì í kú’ (12) ‘O ti mọ́ jù láti máa wo ohun búburú’ (13) 2 “Èmi yóò máa ṣọ́nà kí n lè mọ ohun tí yóò sọ” (1) Èsì tí Jèhófà fún wòlíì náà (2-20) ‘Ṣáà máa retí ìran náà’ (3) Ìṣòtítọ́ yóò mú kí olódodo máa wà láàyè (4) Nǹkan márùn-ún tó mú kí àwọn ará Kálídíà gbé (6-20) Gbogbo ayé yóò ní ìmọ̀ nípa Jèhófà (14) 3 Wòlíì náà bẹ Jèhófà pé kó gbé ìgbésẹ̀ (1-19) Ọlọ́run yóò gba àwọn ẹni àmì òróró rẹ̀ là (13) Máa yọ̀ nítorí Jèhófà láìka wàhálà sí (17, 18) Pa Dà Èyí Tó Kàn Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Hábákúkù—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí BÍBÉLÌ MÍMỌ́ TI ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN (TÍ A TÚN ṢE LỌ́DÚN 2018) Hábákúkù—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Yorùbá Hábákúkù—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1001061100/univ/wpub/1001061100_univ_sqr_xl.jpg nwt Hábákúkù ojú ìwé 1268-1269