YAN Ọ̀KAN Ìwé Bíbélì Jẹ́nẹ́sísì Ẹ́kísódù Léfítíkù Nọ́ńbà Diutarónómì Jóṣúà Àwọn Onídàájọ́ Rúùtù 1 Sámúẹ́lì 2 Sámúẹ́lì 1 Àwọn Ọba 2 Àwọn Ọba 1 Kíróníkà 2 Kíróníkà Ẹ́sírà Nehemáyà Ẹ́sítà Jóòbù Sáàmù Òwe Oníwàásù Orin Sólómọ́nì Àìsáyà Jeremáyà Ìdárò Ìsíkíẹ́lì Dáníẹ́lì Hósíà Jóẹ́lì Émọ́sì Ọbadáyà Jónà Míkà Náhúmù Hábákúkù Sefanáyà Hágáì Sekaráyà Málákì Mátíù Máàkù Lúùkù Jòhánù Ìṣe Róòmù 1 Kọ́ríńtì 2 Kọ́ríńtì Gálátíà Éfésù Fílípì Kólósè 1 Tẹsalóníkà 2 Tẹsalóníkà 1 Tímótì 2 Tímótì Títù Fílémónì Hébérù Jémíìsì 1 Pétérù 2 Pétérù 1 Jòhánù 2 Jòhánù 3 Jòhánù Júùdù Ìfihàn Orí 1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 Lẹ́tà Kejì sí Àwọn Ará Kọ́ríńtì Orí 1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí 1 Ìkíni (1, 2) Ọlọ́run ń tù wá nínú nínú gbogbo ìpọ́njú wa (3-11) Ìrìn àjò Pọ́ọ̀lù yí pa dà (12-24) 2 Ó ń wu Pọ́ọ̀lù láti mú kí wọ́n láyọ̀ (1-4) Ẹlẹ́ṣẹ̀ tí wọ́n dárí jì, tí wọ́n sì gbà pa dà (5-11) Pọ́ọ̀lù lọ sí Tíróásì àti Makedóníà (12, 13) Iṣẹ́ òjíṣẹ́ jẹ́ ìjáde àwọn tó ń yọ ayọ̀ ìṣẹ́gun (14-17) A kì í ṣe akirità ọ̀rọ̀ Ọlọ́run (17) 3 Lẹ́tà ìdámọ̀ràn (1-3) Àwọn òjíṣẹ́ májẹ̀mú tuntun (4-6) Ògo májẹ̀mú tuntun ta yọ (7-18) 4 Ìmọ́lẹ̀ ìhìn rere (1-6) Ojú inú àwọn aláìgbàgbọ́ fọ́ (4) Ìṣúra nínú àwọn ohun èlò tí a fi amọ̀ ṣe (7-18) 5 Gbígbé ibùgbé ọ̀run wọ̀ (1-10) Iṣẹ́ òjíṣẹ́ ìpadàrẹ́ (11-21) Ẹ̀dá tuntun (17) Ikọ̀ fún Kristi (20) 6 Kí a má ṣi inú rere Ọlọ́run lò (1, 2) Bí iṣẹ́ òjíṣẹ́ Pọ́ọ̀lù ṣe rí (3-13) Ẹ má fi àìdọ́gba so pọ̀ (14-18) 7 Ká wẹ ara wa mọ́ kúrò nínú ẹ̀gbin (1) Inú Pọ́ọ̀lù dùn sí àwọn ará Kọ́ríńtì (2-4) Títù mú ìròyìn rere wá (5-7) Ìbànújẹ́ ní ọ̀nà Ọlọ́run àti ìrònúpìwàdà (8-16) 8 Wọ́n kó ọrẹ jọ fún àwọn Kristẹni tó wà ní Jùdíà (1-15) Wọ́n fẹ́ rán Títù lọ sí Kọ́ríńtì (16-24) 9 Ó fún wọn níṣìírí láti máa fúnni (1-15) Ọlọ́run nífẹ̀ẹ́ ẹni tó ń fúnni pẹ̀lú ìdùnnú (7) 10 Pọ́ọ̀lù gbèjà iṣẹ́ òjíṣẹ́ rẹ̀ (1-18) Àwọn ohun ìjà wa kì í ṣe ti ara (4, 5) 11 Pọ́ọ̀lù àti àwọn àpọ́sítélì adára-má-kù-síbì-kan (1-15) Àwọn ìṣòro Pọ́ọ̀lù bó ṣe jẹ́ àpọ́sítélì (16-33) 12 Àwọn ìran tí Pọ́ọ̀lù rí (1-7a) ‘Ẹ̀gún nínú ara’ Pọ́ọ̀lù (7b-10) Àwọn àpọ́sítélì adára-má-kù-síbìkan ò sàn jù ú lọ (11-13) Bí ọ̀rọ̀ àwọn ará Kọ́ríńtì ṣe jẹ Pọ́ọ̀lù lógún (14-21) 13 Ìkìlọ̀ ìkẹyìn àti ọ̀rọ̀ ìyànjú (1-14) “Ẹ máa dán ara yín wò bóyá ẹ wà nínú ìgbàgbọ́” (5) Ẹ máa ṣe ìyípadà; ẹ máa ronú níṣọ̀kan (11) Pa Dà Èyí Tó Kàn Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ 2 Kọ́ríńtì—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí BÍBÉLÌ MÍMỌ́ TI ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN (TÍ A TÚN ṢE LỌ́DÚN 2018) 2 Kọ́ríńtì—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Yorùbá 2 Kọ́ríńtì—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1001061100/univ/wpub/1001061100_univ_sqr_xl.jpg nwt 2 Kọ́ríńtì ojú ìwé 1538-1539