YAN Ọ̀KAN Ìwé Bíbélì Jẹ́nẹ́sísì Ẹ́kísódù Léfítíkù Nọ́ńbà Diutarónómì Jóṣúà Àwọn Onídàájọ́ Rúùtù 1 Sámúẹ́lì 2 Sámúẹ́lì 1 Àwọn Ọba 2 Àwọn Ọba 1 Kíróníkà 2 Kíróníkà Ẹ́sírà Nehemáyà Ẹ́sítà Jóòbù Sáàmù Òwe Oníwàásù Orin Sólómọ́nì Àìsáyà Jeremáyà Ìdárò Ìsíkíẹ́lì Dáníẹ́lì Hósíà Jóẹ́lì Émọ́sì Ọbadáyà Jónà Míkà Náhúmù Hábákúkù Sefanáyà Hágáì Sekaráyà Málákì Mátíù Máàkù Lúùkù Jòhánù Ìṣe Róòmù 1 Kọ́ríńtì 2 Kọ́ríńtì Gálátíà Éfésù Fílípì Kólósè 1 Tẹsalóníkà 2 Tẹsalóníkà 1 Tímótì 2 Tímótì Títù Fílémónì Hébérù Jémíìsì 1 Pétérù 2 Pétérù 1 Jòhánù 2 Jòhánù 3 Jòhánù Júùdù Ìfihàn Orí 1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 14 15 16 17 18 19 20 21 22 Ìwé Àwọn Ọba Kìíní Orí 1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 14 15 16 17 18 19 20 21 22 Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí 1 Dáfídì àti Ábíṣágì (1-4) Ádóníjà wá ọ̀nà láti gorí ìtẹ́ (5-10) Nátánì àti Bátí-ṣébà gbé ìgbésẹ̀ (11-27) Dáfídì pàṣẹ pé kí wọ́n fòróró yan Sólómọ́nì (28-40) Ádóníjà sá lọ sí ibi pẹpẹ (41-53) 2 Dáfídì fún Sólómọ́nì ní ìtọ́ni (1-9) Dáfídì kú; Sólómọ́nì gorí ìtẹ́ (10-12) Ọ̀tẹ̀ Ádóníjà yọrí sí ikú fún un (13-25) Ọba lé Ábíátárì kúrò lẹ́nu iṣẹ́; ó pa Jóábù (26-35) Wọ́n pa Ṣíméì (36-46) 3 Sólómọ́nì fẹ́ ọmọ Fáráò (1-3) Jèhófà fara han Sólómọ́nì lójú àlá (4-15) Sólómọ́nì béèrè ọgbọ́n (7-9) Sólómọ́nì dá ẹjọ́ láàárín àwọn ìyá méjì (16-28) 4 Ìjọba Sólómọ́nì (1-19) Àwọn èèyàn láásìkí nígbà àkóso Sólómọ́nì (20-28) Àwọn èèyàn wà láàbò lábẹ́ àjàrà àti lábẹ́ igi ọ̀pọ̀tọ́ (25) Ọgbọ́n Sólómọ́nì àti àwọn òwe rẹ̀ (29-34) 5 Ọba Hírámù pèsè àwọn ohun èlò ìkọ́lé (1-12) Àwọn tí Sólómọ́nì ní kó máa ṣiṣẹ́ fún òun (13-18) 6 Sólómọ́nì kọ́ tẹ́ńpìlì (1-38) Yàrá inú lọ́hùn-ún (19-22) Àwọn kérúbù (23-28) Àwọn ohun gbígbẹ́, àwọn ilẹ̀kùn, àgbàlá inú (29-36) Iṣẹ́ kíkọ́ tẹ́ńpìlì parí ní nǹkan bí ọdún méje (37, 38) 7 Ààfin Sólómọ́nì (1-12) Hírámù tó jẹ́ akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ ran Sólómọ́nì lọ́wọ́ (13-47) Àwọn òpó bàbà méjì (15-22) Òkun tí a fi irin rọ (23-26) Àwọn kẹ̀kẹ́ ẹrù mẹ́wàá àti àwọn bàsíà bàbà (27-39) Wọ́n parí àwọn ohun èlò tí wọ́n fi wúrà ṣe (48-51) 8 Wọ́n gbé Àpótí wọnú tẹ́ńpìlì (1-13) Sólómọ́nì bá àwọn èèyàn sọ̀rọ̀ (14-21) Àdúrà tí Sólómọ́nì fi ya tẹ́ńpìlì sí mímọ́ (22-53) Sólómọ́nì súre fún àwọn èèyàn náà (54-61) Àwọn ẹbọ àti àjọyọ̀ ìyàsímímọ́ (62-66) 9 Jèhófà tún fara han Sólómọ́nì (1-9) Ẹ̀bùn tí Sólómọ́nì fún Ọba Hírámù (10-14) Oríṣiríṣi iṣẹ́ ìkọ́lé tí Sólómọ́nì ṣe (15-28) 10 Ọbabìnrin Ṣébà ṣèbẹ̀wò sọ́dọ̀ Sólómọ́nì (1-13) Ọrọ̀ rẹpẹtẹ tí Sólómọ́nì ní (14-29) 11 Àwọn ìyàwó Sólómọ́nì yí i lọ́kàn pa dà (1-13) Àwọn alátakò dìde sí Sólómọ́nì (14-25) Ọlọ́run ṣèlérí ẹ̀yà mẹ́wàá fún Jèróbóámù (26-40) Sólómọ́nì kú; wọ́n fi Rèhóbóámù jọba (41-43) 12 Ìdáhùn líle tí Rèhóbóámù fún àwọn èèyàn (1-15) Ẹ̀yà mẹ́wàá yapa (16-19) Wọ́n fi Jèróbóámù jẹ ọba Ísírẹ́lì (20) Ọlọ́run ní kí Rèhóbóámù má ṣe bá Ísírẹ́lì jà (21-24) Ìjọsìn ère ọmọ màlúù tí Jèróbóámù gbé kalẹ̀ (25-33) 13 Àsọtẹ́lẹ̀ sórí pẹpẹ tó wà ní Bẹ́tẹ́lì (1-10) Pẹpẹ là sọ́tọ̀ọ̀tọ̀ (5) Èèyàn Ọlọ́run ṣàìgbọràn (11-34) 14 Àsọtẹ́lẹ̀ tí Áhíjà sọ sórí Jèróbóámù (1-20) Rèhóbóámù ṣàkóso lórí Júdà (21-31) Ṣíṣákì ya wọ Jerúsálẹ́mù (25, 26) 15 Ábíjámù di ọba Júdà (1-8) Ásà di ọba Júdà (9-24) Nádábù di ọba Ísírẹ́lì (25-32) Bááṣà di ọba Ísírẹ́lì (33, 34) 16 Ìdájọ́ Jèhófà lórí Bááṣà (1-7) Élà di ọba Ísírẹ́lì (8-14) Símírì di ọba Ísírẹ́lì (15-20) Ómírì di ọba Ísírẹ́lì (21-28) Áhábù di ọba Ísírẹ́lì (29-33) Híélì tún Jẹ́ríkò kọ́ (34) 17 Wòlíì Èlíjà sọ tẹ́lẹ̀ pé ọ̀dá máa wà (1) Àwọn ẹyẹ ìwò bọ́ Èlíjà (2-7) Èlíjà dé sọ́dọ̀ opó kan ní Sáréfátì (8-16) Ọmọ opó náà kú, ó sì jíǹde (17-24) 18 Èlíjà pàdé Ọbadáyà àti Áhábù (1-18) Èlíjà àti àwọn wòlíì Báálì ní Kámẹ́lì (19-40) ‘Wọ́n ń ṣiyèméjì’ (21) Ọ̀dá ọlọ́dún mẹ́ta àti ààbọ̀ dópin (41-46) 19 Èlíjà sá lọ nítorí ìbínú Jésíbẹ́lì (1-8) Jèhófà fara han Èlíjà ní Hórébù (9-14) Ọlọ́run ní kí Èlíjà fòróró yan Hásáẹ́lì, Jéhù àti Èlíṣà (15-18) Ọlọ́run yan Èlíṣà sí ipò Èlíjà (19-21) 20 Àwọn ará Síríà gbógun ti Áhábù (1-12) Áhábù ṣẹ́gun àwọn ará Síríà (13-34) Àsọtẹ́lẹ̀ lórí Áhábù (35-43) 21 Ọgbà àjàrà Nábótì wọ Áhábù lójú (1-4) Jésíbẹ́lì fa ikú Nábótì (5-16) Iṣẹ́ tí Èlíjà jẹ́ fún Áhábù (17-26) Áhábù rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀ (27-29) 22 Àjọṣe Jèhóṣáfátì àti Áhábù (1-12) Mikáyà sọ tẹ́lẹ̀ pé wọ́n máa ṣẹ́gun Áhábù (13-28) Ẹ̀mí tó máa tan Áhábù (21, 22) Wọ́n pa Áhábù ní Ramoti-gílíádì (29-40) Jèhóṣáfátì ṣàkóso lórí Júdà (41-50) Ahasáyà di ọba Ísírẹ́lì (51-53) Pa Dà Èyí Tó Kàn Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ 1 Àwọn Ọba—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí BÍBÉLÌ MÍMỌ́ TI ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN (TÍ A TÚN ṢE LỌ́DÚN 2018) 1 Àwọn Ọba—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Yorùbá 1 Àwọn Ọba—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1001061100/univ/wpub/1001061100_univ_sqr_xl.jpg nwt 1 Àwọn Ọba ojú ìwé 469-470