YAN Ọ̀KAN Ìwé Bíbélì Jẹ́nẹ́sísì Ẹ́kísódù Léfítíkù Nọ́ńbà Diutarónómì Jóṣúà Àwọn Onídàájọ́ Rúùtù 1 Sámúẹ́lì 2 Sámúẹ́lì 1 Àwọn Ọba 2 Àwọn Ọba 1 Kíróníkà 2 Kíróníkà Ẹ́sírà Nehemáyà Ẹ́sítà Jóòbù Sáàmù Òwe Oníwàásù Orin Sólómọ́nì Àìsáyà Jeremáyà Ìdárò Ìsíkíẹ́lì Dáníẹ́lì Hósíà Jóẹ́lì Émọ́sì Ọbadáyà Jónà Míkà Náhúmù Hábákúkù Sefanáyà Hágáì Sekaráyà Málákì Mátíù Máàkù Lúùkù Jòhánù Ìṣe Róòmù 1 Kọ́ríńtì 2 Kọ́ríńtì Gálátíà Éfésù Fílípì Kólósè 1 Tẹsalóníkà 2 Tẹsalóníkà 1 Tímótì 2 Tímótì Títù Fílémónì Hébérù Jémíìsì 1 Pétérù 2 Pétérù 1 Jòhánù 2 Jòhánù 3 Jòhánù Júùdù Ìfihàn Orí 1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 14 15 16 17 18 19 20 21 22 Ìwé Ìfihàn Orí 1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 14 15 16 17 18 19 20 21 22 Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí 1 Ìfihàn látọ̀dọ̀ Ọlọ́run nípasẹ̀ Jésù (1-3) Ìkíni sí àwọn ìjọ méje (4-8) “Èmi ni Ááfà àti Ómégà” (8) Jòhánù wà ní ọjọ́ Olúwa nípasẹ̀ ìmísí (9-11) Ìran Jésù tí a ṣe lógo (12-20) 2 Iṣẹ́ tó rán sí Éfésù (1-7), Símínà (8-11), Págámù (12-17) àti Tíátírà (18-29) 3 Iṣẹ́ tó rán sí Sádísì (1-6), Filadéfíà (7-13) àti Laodíkíà (14-22) 4 Ìran nípa bí ìtẹ́ Jèhófà ṣe rí lókè ọ̀run (1-11) Jèhófà jókòó sórí ìtẹ́ rẹ̀ (2) Àwọn àgbààgbà 24 wà lórí ìtẹ́ (4) Ẹ̀dá alààyè mẹ́rin náà (6) 5 Àkájọ ìwé tó ní èdìdì méje (1-5) Ọ̀dọ́ Àgùntàn gba àkájọ ìwé náà (6-8) Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà ló yẹ kó ṣí àwọn èdìdì náà (9-14) 6 Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà ṣí èdìdì mẹ́fà àkọ́kọ́ (1-17) Ẹni tó ń ṣẹ́gun jókòó sórí ẹṣin funfun náà (1, 2) Ẹni tó gun ẹṣin aláwọ̀ iná mú àlàáfíà kúrò (3, 4) Ẹni tó gun ẹṣin dúdú máa mú ìyàn wá (5, 6) Ikú ni orúkọ ẹni tó gun ẹṣin ràndánràndán (7, 8) Àwọn tí wọ́n pa wà lábẹ́ pẹpẹ (9-11) Ìmìtìtì ilẹ̀ tó lágbára (12-17) 7 Áńgẹ́lì mẹ́rin di atẹ́gùn tó ń fa ìparun mú (1-3) A gbé èdìdì lé 144,000 (4-8) Ogunlọ́gọ̀ èèyàn wọ aṣọ funfun (9-17) 8 A ṣí èdìdì keje (1-6) Kàkàkí mẹ́rin àkọ́kọ́ dún (7-12) A kéde ìyọnu mẹ́ta (13) 9 Kàkàkí karùn-ún (1-11) Ìyọnu kan kọjá, méjì míì ń bọ̀ (12) Kàkàkí kẹfà (13-21) 10 Áńgẹ́lì alágbára mú àkájọ ìwé kékeré dání (1-7) “A ò ní fi falẹ̀ mọ́” (6) Àṣírí mímọ́ wá sí òpin (7) Jòhánù jẹ àkájọ ìwé kékeré náà (8-11) 11 Àwọn ẹlẹ́rìí méjì (1-13) Àsọtẹ́lẹ̀ fún 1,260 ọjọ́ nínú aṣọ ọ̀fọ̀ (3) Wọ́n pa wọ́n, àmọ́ wọn ò sin wọ́n (7-10) Wọ́n pa dà wà láàyè lẹ́yìn ọjọ́ mẹ́ta àti ààbọ̀ (11, 12) Ìyọnu kejì kọjá, ìkẹta ń bọ̀ (14) Kàkàkí keje (15-19) Ìjọba Olúwa wa àti ti Kristi rẹ̀ (15) Ó máa run àwọn tó ń run ayé (18) 12 Obìnrin náà, ọmọkùnrin náà àti dírágónì (1-6) Máíkẹ́lì bá dírágónì náà jà (7-12) A ju dírágónì náà sí ayé (9) Èṣù mọ̀ pé ìgbà díẹ̀ ló kù fún òun (12) Dírágónì ṣe inúnibíni sí obìnrin náà (13-17) 13 Ẹranko olórí méje jáde látinú òkun (1-10) Ẹranko oníwo méjì jáde látinú ayé (11-13) Ère ẹranko olórí méje náà (14, 15) Àmì àti nọ́ńbà ẹranko náà (16-18) 14 Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà àti 144,000 (1-5) Iṣẹ́ tí àwọn áńgẹ́lì mẹ́ta jẹ́ (6-12) Áńgẹ́lì tó ń fò lójú ọ̀run ń kéde ìhìn rere (6, 7) Aláyọ̀ ni àwọn tó kú ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Kristi (13) Wọ́n máa kórè ayé lẹ́ẹ̀mejì (14-20) 15 Áńgẹ́lì méje ní ìyọnu méje (1-8) Orin Mósè àti ti Ọ̀dọ́ Àgùntàn (3, 4) 16 Abọ́ méje ti ìbínú Ọlọ́run (1-21) Wọ́n dà á sórí ayé (2), sínú òkun (3), sínú àwọn odò àti ìsun omi (4-7), sórí oòrùn (8, 9), sórí ìtẹ́ ẹranko náà (10, 11), sínú odò Yúfírétì (12-16) àti sínú afẹ́fẹ́ (17-21) Ogun Ọlọ́run ní Amágẹ́dọ́nì (14, 16) 17 Ìdájọ́ “Bábílónì Ńlá” (1-18) Aṣẹ́wó ńlá náà jókòó sórí ẹranko aláwọ̀ rírẹ̀dòdò (1-3) Ẹranko náà ‘wà tẹ́lẹ̀, àmọ́ kò sí, síbẹ̀ ó máa jáde látinú ọ̀gbun àìnísàlẹ̀’ (8) Ìwo mẹ́wàá máa bá Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà jà (12-14) Ìwo mẹ́wàá máa kórìíra aṣẹ́wó náà (16, 17) 18 “Bábílónì Ńlá” ṣubú (1-8) “Ẹ jáde kúrò nínú rẹ̀, ẹ̀yin èèyàn mi” (4) Wọ́n ń ṣọ̀fọ̀ ìṣubú Bábílónì (9-19) Wọ́n ń yọ̀ ní ọ̀run torí Bábílónì ṣubú (20) A máa ju Bábílónì sínú òkun bí òkúta (21-24) 19 Ẹ yin Jáà, torí àwọn ìdájọ́ rẹ̀ (1-10) Ìgbéyàwó Ọ̀dọ́ Àgùntàn (7-9) Ẹni tó gun ẹṣin funfun (11-16) Oúnjẹ alẹ́ ńlá ti Ọlọ́run (17, 18) A ṣẹ́gun ẹranko náà (19-21) 20 A de Sátánì fún 1,000 ọdún (1-3) Àwọn tó máa jọba pẹ̀lú Kristi fún 1,000 ọdún (4-6) A tú Sátánì sílẹ̀, àmọ́ lẹ́yìn náà, a pa á run (7-10) A ṣèdájọ́ àwọn òkú níwájú ìtẹ́ náà (11-15) 21 Ọ̀run tuntun àti ayé tuntun (1-8) Ikú kò sí mọ́ (4) Ohun gbogbo di tuntun (5) Bí Jerúsálẹ́mù tuntun ṣe rí (9-27) 22 Odò omi ìyè (1-5) Ìparí (6-21) ‘Wá! Gba omi ìyè lọ́fẹ̀ẹ́’ (17) “Máa bọ̀, Jésù Olúwa” (20) Pa Dà Èyí Tó Kàn Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Ìfihàn—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí BÍBÉLÌ MÍMỌ́ TI ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN (TÍ A TÚN ṢE LỌ́DÚN 2018) Ìfihàn—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Yorùbá Ìfihàn—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1001061100/univ/wpub/1001061100_univ_sqr_xl.jpg nwt Ìṣípayá ojú ìwé 1633-1634