YAN Ọ̀KAN Ìwé Bíbélì Jẹ́nẹ́sísì Ẹ́kísódù Léfítíkù Nọ́ńbà Diutarónómì Jóṣúà Àwọn Onídàájọ́ Rúùtù 1 Sámúẹ́lì 2 Sámúẹ́lì 1 Àwọn Ọba 2 Àwọn Ọba 1 Kíróníkà 2 Kíróníkà Ẹ́sírà Nehemáyà Ẹ́sítà Jóòbù Sáàmù Òwe Oníwàásù Orin Sólómọ́nì Àìsáyà Jeremáyà Ìdárò Ìsíkíẹ́lì Dáníẹ́lì Hósíà Jóẹ́lì Émọ́sì Ọbadáyà Jónà Míkà Náhúmù Hábákúkù Sefanáyà Hágáì Sekaráyà Málákì Mátíù Máàkù Lúùkù Jòhánù Ìṣe Róòmù 1 Kọ́ríńtì 2 Kọ́ríńtì Gálátíà Éfésù Fílípì Kólósè 1 Tẹsalóníkà 2 Tẹsalóníkà 1 Tímótì 2 Tímótì Títù Fílémónì Hébérù Jémíìsì 1 Pétérù 2 Pétérù 1 Jòhánù 2 Jòhánù 3 Jòhánù Júùdù Ìfihàn Orí 1 2 3 4 5 Ìwé Ìdárò Orí 1 2 3 4 5 Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí 1 A fi Jerúsálẹ́mù wé obìnrin opó Ó dá jókòó, a sì ti pa á tì (1) Ẹ̀ṣẹ̀ ńlá tí Síónì dá (8, 9) Ọlọ́run kọ Síónì sílẹ̀ (12-15) Kò sí ẹni tó máa tu Síónì nínú (17) 2 Ìbínú Jèhófà lórí Jerúsálẹ́mù Kò fi àánú hàn (2) Jèhófà ṣe bí ọ̀tá sí i (5) Jeremáyà sunkún nítorí Síónì (11-13) Àwọn tó ń kọjá lójú ọ̀nà fi ìlú tó rẹwà tẹ́lẹ̀ ṣe yẹ̀yẹ́ (15) Àwọn ọ̀tá ń yọ̀ lórí ìṣubú Síónì (17) 3 Jeremáyà sọ bí nǹkan ṣe rí lára rẹ̀ àti ìrètí rẹ̀ ‘Màá fi sùúrù dúró dè ọ́’ (21) Tuntun ni àánú Ọlọ́run láràárọ̀ (22, 23) Ọlọ́run jẹ́ ẹni rere sí àwọn tó ní ìrètí nínú rẹ̀ (25) Ó dára kí àwọn ọ̀dọ́ ru àjàgà (27) Ọlọ́run fi àwọsánmà dí ọ̀nà tó lọ sọ́dọ̀ rẹ̀ (43, 44) 4 Ìnira tó dé bá Jerúsálẹ́mù nígbà tí wọ́n dó tì í Àìsí oúnjẹ (4, 5, 9) Àwọn obìnrin ń se àwọn ọmọ wọn (10) Jèhófà ti da ìbínú rẹ̀ jáde (11) 5 Àdúrà ìpadàbọ̀sípò tí àwọn èèyàn gbà “Rántí ohun tó ti ṣẹlẹ̀ sí wa” (1) ‘A gbé; a ti dẹ́ṣẹ̀’ (16) ‘Mú wa pa dà, Jèhófà’ (21) “Sọ ọjọ́ wa di ọ̀tun” (21) Pa Dà Èyí Tó Kàn Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Ìdárò—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí BÍBÉLÌ MÍMỌ́ TI ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN (TÍ A TÚN ṢE LỌ́DÚN 2018) Ìdárò—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Yorùbá Ìdárò—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1001061100/univ/wpub/1001061100_univ_sqr_xl.jpg nwt Ìdárò ojú ìwé 1118