Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ìwé Ẹ́sítà

Orí

1 2 3 4 5 6 7 8 9 10

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

  • 1

    • Ọba Ahasuérúsì se àsè ńlá ní Ṣúṣánì (1-9)

    • Fáṣítì Ayaba kò ṣègbọràn (10-12)

    • Ọba fọ̀rọ̀ lọ àwọn amòye rẹ̀ (13-20)

    • Wọ́n fi àṣẹ ọba ránṣẹ́ (21, 22)

  • 2

    • Wọ́n wá ayaba tuntun (1-14)

    • Ẹ́sítà di ayaba (15-20)

    • Módékáì tú àṣírí àwọn ọlọ̀tẹ̀ (21-23)

  • 3

    • Ọba gbé Hámánì ga (1-4)

    • Hámánì gbèrò láti pa àwọn Júù run (5-15)

  • 4

    • Módékáì ṣọ̀fọ̀ (1-5)

    • Módékáì ní kí Ẹ́sítà bá àwọn bẹ ọba (6-17)

  • 5

    • Ẹ́sítà wá síwájú ọba (1-8)

    • Hámánì ń bínú, ó sì ń gbéra ga (9-14)

  • 6

    • Ọba dá Módékáì lọ́lá (1-14)

  • 7

    • Ẹ́sítà tú Hámánì fó (1-6a)

    • Wọ́n gbé Hámánì kọ́ sórí òpó igi tó ṣe (6b-10)

  • 8

    • Ọba gbé Módékáì ga (1, 2)

    • Ẹ́sítà bẹ ọba (3-6)

    • Àṣẹ tí ọba fi ta ko àṣẹ àkọ́kọ́ (7-14)

    • Àwọn Júù rí ìtura, wọ́n sì ń yọ̀ (15-17)

  • 9

    • Àwọn Júù ṣẹ́gun (1-19)

    • Wọ́n dá àjọyọ̀ Púrímù sílẹ̀ (20-32)

  • 10

    • Módékáì di ẹni ńlá (1-3)